Aso Oge Tuntun Kim Ni Ilu New York

Bi eniyan ba gbe aso lece fun sabere-dowo ti ori re pe, ti iru lace bee ba je oniho lara dandan ni ki tailor o wa ogbon da lati fi aso alawo iru lace bee te e lati inu ko maa ba fi ihoho gbogbo ara sile tan.

Sugbon Kim Kardashian gan-an lo so fun designer wi pe ko file beyen, ani ko wa beyen lai fi ohunkohun bo lace naa lati inu.

Awotele omobirin naa ko nira lati ri rara eleyii ti won ka gege bi Aso Oge Tuntun.

Abi eyin fe so fun mi wi pe e ko ri awotele omobirin naa?
Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com
www.eventradiofm.com
Whatsapp +2348032394964
BBM pin D60D41BD
BBM channel C004829AB

0 comments:

Post a Comment